Ramadan Kareem (Lyrics)
"Ramadan Kareem" Lyrics
Sari
Sari tito Muslim e dide nle kejeun o
Ehn losan ramadan
Oju mi tiri losan ramadan
Bon gbon je wa mio ni le je
(why why why)
Bon gbomi wa mio ni le mu o
Agba to lo min ninu
O kin pariwo moti n gba awe o
Awe atan oju ati ajosan
Awe atan oju ati ajosan
Irun tito ki elo bori
Saari ti to je o ah
Edie nile Elo se jije
Edide nile E figbo sile
Edie nile o Elo se jije
Edide nile o E figbo sile
Sari tito Muslim e dide nle kejeun o
Ehn losan ramadan
Oju mi tiri losan ramadan
Bon gbon je wa mio ni le je
( why why why )
Bon gbomi wa mio ni le mu o
Agba to lo min ninu
o kin pariwo moti n gba awe o
Èyè fa baki losan ramadan
Èyé gbe olosho losan Ramadan
Emashey sha ishe ninu Ramadan
Oshi tun we oshe ninu Ramadan